Kikida Agbara Download, Video and Lyrics | Solabomi
Nigerian Gospel Music Minister, Worship Leader, Solabomi releases powerful single titled “Kikida Agbara“.
God is full of Power, He does the impossible and changes the unchangeable.
OLORUN NI KIKIDA AGBARA.
Lyrics for Kikida Agbara By Solabomi
[Chorus]
Iwo ni kikida agbara o
Olorun iwo ni kiki da agbara
Jesu iwo ni kiki da agbara
Agbara to wole iku
Agbara to wole aisan pale
Agbara to ji oku dide
Agbara o
Agbara to da aye
Agbara to da orun
Agbara to la’na sinu okun pupa
Oloju gborogodo to ka gbogbo agbanla aiye
Alapa robirobi
Opapa pa’bida so’bi direre o
Gbanigbani to ngba’ni lojo ogun le
Alagbara nla to gbani lowo alagbara aiye
Alagbara aiye to fe fowo agbara gba’ni loju
Baba mi fiwon se yeye ni gbangban o
Iwo lapa’ni ji’ni
Iwo lamu’ni so’ni
Iwo lade’ni tu’ni o
Mu’nimu’ni So’niso’ni D’enide’ni
Tani kafi o we
[Chorus]
Mo niwo ni kikida agbara
Aiyeraye, iwo ni kiki da agbara
Jesu, iwo ni kiki da agbara
Oba nla, Oba to lo kanrinkese o
Alagbara o/2x
Agbara to s’ohun gbogbo
Ogo to ngb’enu ogo sogo
Ogo to ran ogo nise
Ogo rabata to wo ogo laso
Oro kanka tin ka satani laya
Oro ti npe oro ran nise o, Olorun Iyanu
[Chorus]
Iwo ni kikida Agbara o
Jesu iwo ni kiki da agbara o
Okun ri o o sa o
Jordani ri o, o pada sehin
Awon oke nla won nfo bi agbo niwaju Olorun wa o
Oke kekeke won nfooo bi Od’agutan Kilose o iwo okun ti o fisa o?
Jordani ese to fi pada sehin o?
Wariri iwo ile niwaju Oluwa wa…
Resp: iwo iwo iwo
Call: Majaya lolo
Call: Atofarati bi oke o
Call: Alade ogo to nf’oba d’ade
Call: Oba to ngb’ade lori Oba
Call: baba to nk’oba lorun
Call: Jagunjagun ode orun o
Call: Awon Angeli won nforibale o
Call: Apata Aiyeraiye
Resp: Mimo mimo mimo
Call: Won nko mimo mimo mimo mimo
Call: Oninu funfun oniwa funufun Baba o
Call: Alagbada funfun, Olorun funfun Baba
Call: Alade funfun, Oniwa funfun Baba o
Call: Onje mimo mimo mimo mimo
Call: Aiyeraye Aiyeraye
Call: Oba to joko nibi funfun
Call: Alagbara
Call: Kabio osi o
Download Kikida Agbara By Solabomi (MP3)
Video : Kikida Agbara By Solabomi