O ti mu wa ye Download, Stream and Video By EmmaOMG ft The OhEmGee Choir
A song of celebration, of the Salvation work of Jesus Christ in our lives
Download and Stream O ti mu wa ye By EmmaOMG ft The OhEmGee Choir (MP3)
Lyrics for O ti mu wa ye By EmmaOMG ft The OhEmGee Choir
Ide ti ja o a ti yo
Tori o ti di igbekun ni igbekun
Iye n be o f’eni t’o fe
T’o ba ti wo oju re
Ninu Jesu ni Iye wa o
Wo sa ti owo oju re
So let the Godly rejoice
Let them be glad in your presence
Let them be filled joy
Praise His name who is our essence
Cos we have to the assembly
Of God’s firstborn children o in Heaven
Tori O ti mu wa ye
O ti mu wa ye
O di igbekun ni igbekun o si f’ebun f’awa ayanfe re
O di igbekun ni igbekun o si f’ebun f’awa ayanfe re
O ti mu wa ye
O ti mu wa ye
Ide ti ja o a ti yo
Ide ti ja o a ti yo
Ide ti ja o a ti yo
o o oh oh oh oh oh
Ide ti ja o a ti yo
Iye n be o f’eni t’o fe
T’o ba ti wo oju re
Ninu Jesu ni Iye wa o
Wo sa ti wo oju re
So let the Godly rejoice
Let them be glad in your presence
Let them be filled joy
Praise His name who is our essence
Cos we have to the assembly
Of God’s firstborn children o in Heaven
Tori O ti mu wa ye
O ti mu wa ye
O di igbekun ni igbekun o si f’ebun f’awa ayanfe re
O di igbekun ni igbekun o si f’ebun f’awa ayanfe re
O ti mu wa ye
O ti mu wa ye
O di igbekun ni igbekun o si f’ebun f’awa ayanfe re
O di igbekun ni igbekun o si f’ebun f’awa ayanfe re
O ti mu wa ye
O ti mu wa ye
O ti mu wa ye
O ti mu wa ye
O ti mu wa ye
O ti mu wa ye
O ti mu wa ye
O ti mu wa ye
O ti mu wa ye
O ti mu wa ye
Ibukun ni fun Oluwa ti ko fi wa le awon ota wa l’owo
O ti mu wa ye
O ti mu wa ye
O ti mu wa ye
Okan wa yo bi eye jade kuro ninu okun apeye
Ide ja a ti yo ‘tori o ti mu wa ye
O ti mu wa ye
O ti mu wa ye
Ide ma ti ja o a ti yo
O ti mu wa ye
O ti mu wa ye
O ti mu wa ye
O ti mu wa ye
Ide mi ja mo d’ominira lat’igba
Mo ti gba Jesu
Ijo ope si Baba
Ide mi ja mo d’ominira lat’igba
Mo ti gba Jesu
Ati rami pade
A san gbese mi
Ni’pa eje Jesu
Ati rami pade
A san gbese mi
Ni’pa eje Jesu
Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
E mu ade Oba re wa o
Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
(adlips)
Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Tori ide mi ja mo d’ominira lat’igba
Mo ti gba Jesu
Ati rami pade
A san gbese mi
Ni’pa eje Jesu
Tori O ti mu wa ye
O ti mu wa ye
O ti mu wa ye
(Hallulejah)