Skip to content

Adeyinka Alaseyori – Jesu Nasareti

Jesu Nasareti Download, Stream, Video and Lyrics | Adeyinka Alaseyori

Follow us on all our Social Media Platforms
Instagram:  AdeyinkaAlaseyori
Facebook: Adeyinka Alaseyori
Twitter: Yinkaalaseyori1

Adeyinka Alaseyori - Jesu Nasareti

Download and Stream Jesu Nasareti By Adeyinka Alaseyori (MP3)

DOWNLOAD / STREAM BOOMPLAY

DOWNLOAD / STREAM APPLE

DOWNLOAD / STREAM SPOTIFY

Video : Jesu Nasareti By Adeyinka Alaseyori

JESU NASARETI By Adeyinka Alaseyori

Lyrics for Jesu Nasareti By Adeyinka Alaseyori

Jesu lon da mi lola
Lon da mi lola
Jesu lon segun funmi
Lon segun funmi
Gbogbo eniyan se on da e lola
On da wa lola
Se on segun fun e
On segun fun wa
Oji oku dide
Omu aro lara da
O so agan do lomo
Jesu ti Nasareti o

Oti ya
Jesu ti Nasareti
Ti Nasareti
Oti ranmilowo
Ti Nasareti

Jesu ti Nasareti
Jesu ti Nasareti
Oti ranmilowo
Jesu ti Nasareti

Jesu ti Nasareti
Ti Nasareti
Ewa wo bo se ranmilowo
Ti Nasareti

Jesu ti Nasareti
Jesu ti Nasareti
Oti ranmilowo
Jesu ti Nasareti

Ewa wo bo se se
Ewa wo bo se se
Awa eniyan ojosi
Omu wa losi bi giga
Omu ogo jade
E yen ninu ofo wa
Ebi ore ara
Won lero pe a le de bi
Bio se wo adani waye
To ti wa leyin
Aye wa nba wa dupe
Won ki wa kuorire

Jesu ti Nasareti
Jesu ti Nasareti
Oti ranmilowo
Jesu ti Nasareti
Jesu ti Nasareti
Jesu ti Nasareti
Oti ranmilowo
Jesu ti Nasareti

Eniyan ti se bi eniyan
Olorun duro bi olorun
Lori oro mi
Onwa jo ota mi loju
Eniyan ti sebi eniyan
Olorun jewo agbara
Lori oro mi
Owa ya otami lenu

Jesu ti Nasareti
Jesu ti Nasareti
Oti ranmilowo
Jesu ti Nasareti

Ewa gbo nipa re
Aye e je aso nipa re
Awo kilu mo lonje
Baba dada
Oloyun ara re
O bi ra re
Otun so ra re loruko
Omo alade alafia
Ijoba yio wa lejika re

Jesu ti Nasareti
Jesu ti Nasareti
Oti ranmilowo
Jesu ti Nasareti

Jesu ti Nasareti
Jesu ti Nasareti
Oti ranmilowo
Jesu ti Nasareti

Je je je je je je oh
Jesus
Jesus
Oruko re o lagbara

Jesu ti Nasareti
Jesu ti Nasareti
Oti ranmilowo
Jesu ti Nasareti

Je je je je je je oh
Jesus
Jesus
Oruko yen on gbe ku mio
Jesu ti Nasareti
Jesu ti Nasareti
Oti ranmilowo
Jesu ti Nasareti

Yinka favourite singer
Yin tide o
Alaseyori
Gbogbo aye loti mo
Pe mo ri anu gba gan ni

Jesu ti Nasareti
Jesu ti Nasareti
Oti ranmilowo
Jesu ti Nasareti

Glorious minister
Yin tide o
Alaseyori
Gbogbo aye de loti mo
Mo ri anu gba gidi

Jesu ti Nasareti
Jesu ti Nasareti
Oti ranmilowo
Jesu ti Nasareti

Celebrated minister
Tide o
Global minister lon je
Gbogbo aye loti mo
Pe yinka ri anu gba ni se

Jesu ti Nasareti
Jesu ti Nasareti
Oti ranmilowo
Jesu ti Nasareti

Ape mo ra lan pe temidire
Oje so ti re
Emi ra anu gba
Se wo no ranu gba o

Jesu ti Nasareti
Jesu ti Nasareti
Oti ranmilowo
Jesu ti Nasareti

Je je je je je je oh
Jesus
Jesus
Se oruko yen gbe ku mi

Jesu ti Nasareti
Jesu ti Nasareti
Oti ranmilowo
Jesu ti Nasareti

Je je je je je je oh
Jesus
Jesus
Oruko yen olagbara gan

Jesu ti Nasareti
Jesu ti Nasareti
Oti ranmilowo
Jesu ti Nasareti

Na You wey matter
For my matter
Adaniwaye iwo lo matter
Ninu matter mi
Arugbo ojo
O gbe matter mi sori
Aye wa npa riwo ohun ni
Bio se wo leyin mi
Aye oba yo mio

Jesu ti Nasareti
Jesu ti Nasareti
Oti ranmilowo
Jesu ti Nasareti

Jesu ti Nasareti
Ti Nasareti
E wo bo se gbemi dide
Ti Nasareti o

Jesu ti Nasareti
Jesu ti Nasareti
Oti ranmilowo
Jesu ti Nasareti

Je je je je je je oh
Jesus
Jesus
Oruko yen olagbara gan

Jesu ti Nasareti
Jesu ti Nasareti
Oti ranmilowo
Jesu ti Nasareti

Celebrated minister
Tide o
Yinka alaseyori
Gbogbo aye loti mo
Pe mo ri anu gba ni

Jesu ti Nasareti
Jesu ti Nasareti
Oti ranmilowo
Jesu ti Nasareti

Connect and Follow GospelSongsNG

FACEBOOK TWITTER TELEGRAM

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *