Skip to content

Adejoke Felicia – Ijoba (Kingdom) Ft. Anointing Oluwaseun

Ijoba (Kingdom) Download and Lyrics | Adejoke Felicia Ft. Anointing Oluwaseun

The song IJOBA which means ‘Kingdom‘ in English is a song written by the inspiration of the holy spirit and it’s a song of surrendering to God to take over the situation of our life, and it’s set to be a blessing to everyone.

SOCIAL MEDIA DETAILS:

Facebook: Felicia Adejoke
Instagram: feliciaaderiade
Twitter: FeliciaAderibi2

Download Ijoba (Kingdom) By Adejoke Felicia Ft. Anointing Oluwaseun

Lyrics for Ijoba (Kingdom) By Adejoke Felicia Ft. Anointing Oluwaseun

Chorus:
Ijoba to so nu
Ijoba to sonu bawa wa
Ijoba to Kuna to wa so na afe o
Eleduwa oba ire abe o gba ko so

Solo 1:
On the increase of government Oluwa.
Ninu itesi wa ju ijoba wa Oluwa.
And for peace there will be no end
alafia koni do pin lailai o
Eleduwa oba ire abe o gbakoso

(Back to chorus Ijoba to sonu)

Aye ti fo ju tipe tipe
Idamu ba okan wa baba anbe o, are my aye to wa so na afe o
Eleduwa oba ire abe o gbakoso

(Back to chorus Ijoba to sonu)
.

Solo 3:
I will seek what was lost
Gbogbo owu rara to so nu ni ma gba pada
And bring back what was driven away
Eleduwa oba ire abe o gbakoso

(Back to chorus Ijoba to sonu bawa wa)

Aye ti shina oti pe
Idamu ba okan wa nbe o
Ani lo ite si wa ju oluwa to wa Sona
Idamu ba okan wa nbe o fun atunse
Ninu iporuru okan lan gbe ni gbogbo igba
Wa tun aye wa se

.Aye ti Sina oti pe
Idamu ba okan wa nbe o fun atunse afi oruko nla re be o
Dakun gbakoso

( Back to chorus Ijoba to sonu)

Ijoba Yi sisan ba wa da si
Oni segun nla o
Ani lo re fun iwo San nla
Do ki ta to mo ye wa wo wa San
Sanu… Wa.

( Back to ijoba to sonu)

Download Ijoba (Kingdom) By Adejoke Felicia Ft. Anointing Oluwaseun (MP3)

GET AUDIO

Connect and Follow GospelSongsNG

FACEBOOK TWITTER TELEGRAM

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *