Omo’ba Download, Stream, Video and Lyrics By Pelumi Deborah Ft George Alao
Welcome to the official release of “Omo Oba,” a powerful gospel song by Pelumi Deborah.
Omo Oba – A powerful anthem of identity and purpose in Christ.
In a world where many struggle to find their true identity, Omo Oba is a reminder that as believers, we are the children of the King of Kings. This song speaks to the heart of every listener, calling you to recognize and embrace your divine heritage.
Let this song be a declaration of who you are in Christ—a child of royalty, destined for greatness. As you listen, may you be filled with the confidence and peace that comes from knowing your place in God’s kingdom.
If this song blesses you, don’t forget to like, share, and subscribe. Let’s spread the message of our royal identity far and wide!
Download and Stream Omo’ba By Pelumi Deborah Ft George Alao (MP3)
Lyrics for Omo’ba By Pelumi Deborah Ft George Alao
Sebe mi na re o, Omo Oba
A lemi naa re o, Omo Oba
Sebe mi na re o, Omo Oba
A lemi naa re o, Omo Oba
(why look any further)
Sebe mi na re o, Omo Oba
Eni oba n ke
Eni oba n ge
Eni oba n wo
Eni oba ntoju
Oba lo to mi dagba
Oba lo womi dagba
Oba lo ran mi ni se
Oba lo f’ ami simi lara
Oba lo da ororo demi lori
O f’ade iyin de mi lori
O f’ ade ogo demi lori
O f’ ade ewa demi lori
Ohun lo ni ki n duro dede
O loun wa lehin mi bi akoni eleru
O ni awon omo kiniun
Won a ma se alaini
Ebi a si maa pawon
Sugbon awon to duro de oluwa
Won ko ni s’ alaini ohun to dara
Emi ti gbe oluwa ka iwaju mi nigbagbogbo
Nitori o wa lehin mi eh..
Aki yio si mi nipo
Won o le si mi nipo eh…
Mo ni won o le si mi nipo
Emi o see si nipo
Tori oba lo ran mi nise
Oba lo ran mi nise
Baa ranni nise oba aa fi toba je
Baa ranni nise oba aa fi toba je
Oba lo ran mi nise
Ohun lo ni ki n ma beru
Ohun loni ki n ma foya
Ohun lo ni ki n te siwaju
Seb’ emi naa re oo, Omo Oba
A lemi naa re o om’ oba
(I can’t help it)
Seb’ emi naa re oo eeehhhh
Seb’ emi naa re o om’ oba o eh..
Seb’ emi naa re Omo Oba…
Seb’ emi naa re oo
Ajike
Ajige
Apeke
Asake
Ayanfe
Ololufe mi lo pemi
O ni kin duro deede
O ni kin mase beru
O ni kin mase foya
Seb’ emi na re
Resp: omo’ ba
Seb’ emi na re
Call :
Resp: Omo Oba
Resp: Omo Oba
Resp: Omo Oba
Resp: Omo Oba
Omo Oba, mase beru
Omo Oba, mase foya
Sebe mi na re o, Omo Oba
A lemi naa re o, Omo Oba
Sebe mi na re o, Omo Oba
A lemi naa re o, Omo Oba
Oba n ke mi
Oba n wo mi
Oba lo n dari mi
Emi naa re Omo Oba
Oba n ke mi
Oba n wo mi
Oba lo n dari mi
Emi naa re Omo Oba
Oba n ke mi
Oba n wo mi
Oba lo n dari mi
Emi naa re Omo Oba
Oba n ke mi
Oba n wo mi
Oba lo n dari mi
Emi naa re Omo Oba
Oba n ke mi
Oba n wo mi
Oba lo n dari mi
Emi naa re Omo Oba
Oba n ke mi
Oba n wo mi
Oba lo n dari mi
Emi naa re Omo Oba
Oba n ke mi
Oba n wo mi
Oba lo n dari ese mi
Emi naa re Omo Oba
Oba n ke mi
Oba n wo mi
Oba lo n dari ese mi
Emi naa re Omo Oba
Oba n ke mi
Oba n wo mi
Oba lo n dari ese mi
Emi naa re Omo Oba
Oba n ke mi
Oba n wo mi
Oba lo n dari ese mi
Emi naa re Omo Oba
Video for Omo’ba By Pelumi Deborah Ft George Alao