Skip to content

Mega 99 – Wa Gbo Adura

Wa Gbo Adura Download, Stream, Video and Lyrics | Mega 99

Wa gbo adura mi

Ba mi se ki n le rogo lo laye

Wa gbo adura mi oooo

Ba mi se ki n le rogo lo laye

Wa gbo adura mi, ba mi se ki n le rogo lo laye (Baba)

Wa gbo adura mi, ba mi se ki n le rogo lo laye

Igbe mi ma je o dabi igbe aja niwaju re Olorun mi

Mega 99 Wa Gbo Adura

Download and Stream Wa Gbo Adura By Mega 99 (MP3)

DOWNLOAD / STREAM AUDIO

Video : Wa Gbo Adura By Mega 99

Lyrics for Wa Gbo Adura By Mega 99

Interlude

Wa gbo adura mi

Ba mi se ki n le rogo lo laye

Chorus: Wa gbo adura mi

Ba mi se ki n le rogo lo laye

Wa gbo adura mi oooo

Ba mi se ki n le rogo lo laye

Wa gbo adura mi, ba mi se ki n le rogo lo laye (Baba)

Wa gbo adura mi, ba mi se ki n le rogo lo laye

Igbe mi ma je o dabi igbe aja niwaju re Olorun mi

Igbe mi ma o je dabi igbe agutan niwaju re Olorun mi

Oluwa ma ta mi nu , faanu gba mi

Se ni ko fami mora ooo

Oni majemu ayo

Gbogo mi jade

Chorus …..

Se fun mi nigba ti aso si n duro lejika mi Olorun mo be o

Se funmi nigba ti eyin mi ran egungun

Olorun mi shaanu mi

Ma je ki n ti darugbo tan

Ki ti ma fopa tele

Ki ogo mi to de oo

Tête bamise oo

Ojo ti n lo

Chorus ….

Connect and Follow GospelSongsNG

FACEBOOK TWITTER TELEGRAM

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *