Bi Gbogbo Irun Ori Mi Baje Kiki Ahon Download, Stream, Video and Lyrics | Lady Evang. Toyin Leshi
Gospel music minister, Lady Evang. Toyin Leshi and Her Divine Melodies releases a new single titled “Bi Gbogbo Irun Ori Mi Baje Kiki Ahon”.
Download and Stream Bi Gbogbo Irun Ori Mi Baje Kiki Ahon By Lady Evang. Toyin Leshi (MP3)
Video : Bi Gbogbo Irun Ori Mi Baje Kiki Ahon By Lady Evang. Toyin Leshi
Lyrics for Bi Gbogbo Irun Ori Mi Baje Kiki Ahon By Lady Evang. Toyin Leshi
Bi Gbogbo Irun Ori Mi Baje Kiki Ahon
Bi Gbogbo Irun Ori Mi Baje Kiki Ahon
Bi Gbogbo Irun Ori Mi Baje Kiki Ahon
Ko to lati yin Baba logo
Bí gbogbo irun orí mi jẹ́ kìkì ahọ́n
Kòtó Kòtó láti yín Bàbá lógo
Kòtó kòtò láti yín Bàbá lógo
Kòtó ooo
Bí gbogbo irun orí miii
VOCALS: Bí gbogbo irun orí mi jẹ́ kìkì ahọ́n
Bí gbogbo irun orí mi jẹ́ kìkì ahọ́n
Kòtó Kòtó láti yín Bàbá lógo
Kòtó kòtò láti yín Bàbá lógo
Kòtó ooo
Bí gbogbo irun orí miii
VOCALS: Bí gbogbo irun orí mi jẹ́ kìkì ahọ́n
Bí gbogbo irun orí mi jẹ́ kìkì ahọ́n
Kòtó Kòtó láti yín Bàbá lógo
Kòtó kòtò láti yín Bàbá lógo
Kòtó ooo
Bí gbogbo irun orí miii
VOCALS: Bí gbogbo irun orí mi jẹ́ kìkì ahọ́n
Ona iye ti mo wa yin
Oluwa wa gbe mi ro
Ma ja pade seyin
Jesu wa gbe mi ro
Ona iye ti mo wa yin
Jesus wa gbe mi ro
Ma ja pade seyin
Jesu wa gbe mi ro
Ona iye ti mo wa yin
Jesus wa gbe mi ro
Ma ja pade seyin
Jesu wa gbe mi ro
Ona iye ti mo wa yin
Jesus wa gbe mi ro
Ma ja pade seyin
Jesu wa gbe mi ro
Bí gbogbo irun orí mi jẹ́ kìkì ahọ́n
Kòtó Kòtó láti yín Bàbá lógo
Kòtó kòtò láti yín Bàbá lógo
Kòtó ooo
Bí gbogbo irun orí miii
VOCALS: Bí gbogbo irun orí mi jẹ́ kìkì ahọ́n
Leave a Reply