Jesu Download and Lyrics | Nikki Laoye Ft. Cwesi Oteng
Download Jesu By Nikki Laoye Ft. Cwesi Oteng (MP3)
Lyrics for Jesu By Nikki Laoye Ft. Cwesi Oteng
[Verse 1]
Jesu olufe okan mi
Jesu Olugbala okan mi
O ta eje re sile
Fun irapada mi
[Chorus]
Ibukun atope ni foruko re titilai
Iyin atogo ni, forukore titilai
[Verse 2]
Jesu mi olugbeja mi
Jesu loluso aguntan mi
O wa pelu mi nigba gbogbo
O rin pelu mi emi ki yo beru
[Chorus]
Ibukun atope ni foruko re titilai
Iyin atogo ni forukore titilai
Ibukun atope ni foruko re titilai
Iyin atogo ni forukore titilai
Ibukun atope ni foruko re titilai
Iyin atogo ni forukore titilai
Ibukun atope ni foruko re titilai
Iyin atogo ni forukore titilai
Download Jesu Lyrics (TEXT File)