Iba Download, Stream, Video and Lyrics | Gbenga Akinfenwa Ft. Olayiwola Jagun
It was a little after 3am. While in prayer I heard what seemed like a passing procession of ‘beings’ whisper these words ‘Tooto Ola re Iba’.
This is not an expression I’m used to, and I can’t adequately explain the worship and divine interaction that followed. This recording is our heartfelt, albeit inadequate re-enactment of what goes around the throne. Endless worship, angels crying one to another ‘Holy, Holy Holy’.
As you bask in this sounds, may your heavens be opened. May your eyes be opened. May you ‘see’ God!
Download and Stream Iba By Gbenga Akinfenwa Ft. Olayiwola Jagun (MP3)
Video : Iba By Gbenga Akinfenwa Ft. Olayiwola Jagun
Lyrics for Iba By Gbenga Akinfenwa Ft. Olayiwola Jagun
Morababa, Morababa
Eledumare ooo
To to ola re ba
Iba, iba fun o ooo
Toto ola re iba
Awon angeli won f’ori bale
To to ola re ba
Iba, iba fun o ooo
Toto ola re iba
Morababa, Morababa
Olutoju eniyan
To to ola re ba
Iba, iba fun o ooo
Toto ola re iba
To to ola re ba
Iba, iba fun o ooo
Toto ola re iba
To to ola re iba
Iba, iba fun o ooo
Toto ola re iba
To to ola re iba
Iba, iba fun o ooo
Toto ola re iba
Iba akoda aye oo, iba
Iba aseda orun oo, iba
Ato to gboju le, iba
Ato to farati, iba
Ato to feyin ti, iba
Ato f’ise ogun ran, iba
Asiwaju ogun lalo, iba
Akeyin ogun labo, iba
Oranmonise fayati, iba
Oranmonise pon’mo seyin, iba
Awo igba’run ma gbeje, iba
Awo igba’run ma gbeje ooo, iba
Olowo pin’re pin’re, iba
Olowo ro’bi ro’bi, iba
O pin’re, pin’re kanmi ooo, iba
O pin’re, pin’re kan e ooo, iba
Iba, iba, iba, iba
Iba, iba, iba, iba
Iba, iba, iba, iba
Diving Eulogy
Morababa, Morababa
Eledumare ooo
To to ola re ba
Iba, iba fun o ooo
Toto ola re iba