Skip to content
Home » EmmaOMG Songs » EmmaOMG – E Ti Tobi to

EmmaOMG – E Ti Tobi to

Eti Tobi to Download, Stream, Video and Lyrics By EmmaOMG Ft The OhEmGee Choir, Pelumi Deborah & BBO

EmmaOMG E Ti Tobi to Ft The OhEmGee Choir, Pelumi Deborah & BBO

Download and Stream Eti Tobi to By EmmaOMG Ft The OhEmGee Choir, Pelumi Deborah & BBO (MP3)

DOWNLOAD STREAM BOOMPLAY

DOWNLOAD STREAM APPLE

Lyrics for Eti Tobi to By EmmaOMG Ft The OhEmGee Choir, Pelumi Deborah & BBO

Oluwa tobi ni Sioni
O si j’oba lori orile ede
Je ki won yin oruko re ti o tobi ti osi ni eru

Lead : Gbogbo aye n wariri, ni oruko re
Won n k’orin

Response : Eti tobi to oo
Jesu

Oluwa tobi ni Sioni
O si j’oba lori orile ede
Je ki won yin oruko re ti o tobi ti osi ni eru
E ke Aleluya

Lead : Gbogbo aye n wariri, ni oruko re
Won n k’orin

Response : Eti tobi to oo
Jesu

Lead : Awon orun n s’eleri won foribale niwaju ite re o,

Response : Eti tobi to oo
Jesu

Lead : Won ni Eti tobi to o
oh oh oh Oluwa

Response : Eti tobi to oo
Jesu

Lead : Won ni eti tobi to o,
oh oh oh oh Oluwa wa o

Response : Eti tobi to oo
Jesu

Lead : Awon oke nla nla won foribale o Tori iwo ni ogo ati ola ju oke nla ikogun won ni lo o

Response : Eti tobi to o
Jesu

Lead : Iwo ti Olorun ji dide ninu oku lati gba wa kuro ninu ibinu ti n bo o

Response : Eti tobi to o
Jesu

Lead : Iwo Oluwa Olorun to n gbe larin awon kerubu to po ni ipa ati agbara o

Response : Eti tobi to oo

Jesu

Lead : Ani gbogbo aye n wariri ni oruko re won nkorin ….yeee

Response : Eti tobi to oo
Jesu

Lead : Awon orun n s’eleri won foribale niwaju ite re

Response: Eti tobi to oo
Jesu

Lead : Eti tobi to o

oh oh oh oh Oluwa wa o

Response : Eti tobi to o
Jesu

Lead : Ipekun ola , Ipekun iye ye eh eh eh eti tobi to oh oh oh oh

Response: Eti tobi oo
Jesu

Lead : Ireti wa o , eri wa o oh oh oh eti tobi to oh oh oh

Response : Eti tobi to ooo
Jesu

Lead : Itan sho to wole ro ro ro ro ro Eti tobi to aye ati orun n bo oo

Response : ( Won n juba ) eti tobi to o Jesuuu ( won foribale)

Lead : Jordani ri o o pada seyin ,okun ri o o sa Eti tobi to Olodumare

Response : Eti tobi to o
Jesu

Lead : Abetilukarabiajere baba mi agba oye Eti tobi to oh oh oh oh oh

Response: Eti tobi oo
Jesu

Lead : Tori na gbogbo aye n wariri ni oruko re won nkorin

Response : Eti tobi to o
Jesu

Lead : Awon orun n s’eleri won foribale niwaju ite re eh eh eh

Response : Eti tobi to o
Jesu

Lead : Won ni eti tobi to oo oh oh oh Oluwa wa

Response : Eti tobi to oo
Jesu

Lead : Gbogbo idile Jesse, jesu won nkorin foribale won so wipe

Response : Eti tobi to o
Jesu

Lead : Ipekun ola Ipekun Oro , Ipekun agbara oh eti tobi to Eti tobi to oh oh oh oh oh

Response; Eti tobi to o
Jesu

Lead : Ore ati ola nla ni o wa ni iwaju re ,ipa ati ewa nbe nibi mimo re

Response: Eti tobi to o
Jesu

Lead : Aiikakatan o, Aiibubutan o atobi loye ongbe leyin eni a n da loro oo Eti Eti Eti tobi to o

Response: Eti tobi to o
Jesu

Lead : Jesu gbogbo aye n wariri ni oruko re won nkorin

Response Eti tobi to oo
Jesu

Lead : Awon orun n s’eleri won foribale niwaju ite re ohhhh eh

Response Eti tobi to oo
Jesu

Lead : Won juba fun ajunilo o, eba n juba f’ajunilo eh ,e ba n seba f’ajunilo o,e ba gbo’suba f’ajunilo ,e ba n gbo osuba f’ajunilo o,e ba n kira f’ajunilo o ,e ba n juba f’ajunilo o,e bami juba f’ajunilo e ba n gbo’suba f’ajunilo o ,e ba n seba f’ajunilo o,

Ani gbogbo aye n wariri ni oruko re won nkorin

Eti tobi to o Jesu

Outro
E ba mi juba f’ajunilo
E ba mi juba f’ajunilo
E ba mi juba f’ajunilo
E ba mi juba f’ajunilo

E ba mi juba f’ajunilo
E ba mi juba f’ajunilo
E ba mi juba f’ajunilo
E ba mi juba f’ajunilo

O wa pe l’awon ero mimo l’ona
O si je imole won l’osan l’oru

O wa pe l’awon ero mimo l’ona
O si je imole won l’osan l’oru

Lead : Gbogbo aye n wariri, ni oruko re
Won n k’orin

Response : Eti tobi to oo
Jesu

Outro
E ba mi juba f’ajunilo
E ba mi juba f’ajunilo
E ba mi juba f’ajunilo
E ba mi juba f’ajunilo

Video for Eti Tobi to By EmmaOMG Ft The OhEmGee Choir, Pelumi Deborah & BBO

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *