Skip to content

Fert – Emi Mimo [MP3 and Lyrics]

Emi Mimo Download and Lyrics | FertEmi Mimo Fert

Download Emi Mimo By Fert (MP3)

GET AUDIO

Lyrics for Emi Mimo By Fert

Mo wo ka gbogbo aye pa
Koma de seni ti mo lo pe ni mimo
Gbogbo omo adari hurun pata pata
Iwa ibaje ni won mi wu kiiri
Oro aye toju su mi ohohohoh
Opin aye ti de tan ore mi gbo
Emi mimo ni’e je a jo beere fun
Kaba le dejoba orun si mi ohoh

Emi mimo ni mo fe
Je ko ba le mi oluorun
Ebe mi ma re loni o baba
Emi mimo ni mo fe
Je ko ba le mi oluorun
Ebe mi ma re loni o baba

Mi o fe waye lasan
Bi ejo ori apata
Ebe mi ma re loni o baba
Emi mimo ni mo fe
Je ko ba le mi oluorun
Ebe mi ma re loni o baba

Iwa ese ma mi gbokun si ni abi eyin ori ni
Iwokuwo logbode okunrin atokunrin tun ti n fe ra won
Kini pasito n wa re le alawo (oma se oo)
Eemo lukutu pebe oko tun faya re rubo (ha iru ife wo leyi oo)
Emi mimo le mi n fe jeko ba le mi Oluorun
Ebe mi ma re loni o baba

Emi mimo ni mo fe
Je ko ba le mi oluorun
Ebe mi ma re loni o baba
Emi mimo ni mo fe
Je ko ba le mi oluorun
Ebe mi ma re loni o baba

Mi o fe waye lasan
Bi ejo ori apata
Ebe mi ma re loni o baba
Emi mimo ni mo fe
Je ko ba le mi oluorun
Ebe mi ma re loni o baba

Aye n pare lo ore mi 00
Mase woro aye
Opin aye lawa yioo
Emi n bo kankan ere mi nbe pelumi sa Lolugbala wi funwa
Otilo la ti lo pese aye sile feni bale duro

Download Emi Mimo Lyrics (TEXT File)

GET LYRICS

Connect and Follow GospelSongsNG

FACEBOOK TWITTER TELEGRAM

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *