Skip to content

Elect Temitope – Yoo D’itan

Yoo D’itan Download and Lyrics | Elect Temitope

Elect Temitope Yoo Ditan mp3 image

Download Yoo D’itan By Elect Temitope (MP3)

GET AUDIO

Lyrics for Yoo D’itan By Elect Temitope

Yoo D’ITAN
A d’ohun igbagbe
Ilakoja re oni
A d’iitan

Iyagan Hannah pada d’itan
L’ona iyanu
Ogo gbe Josefu jade
Tubu d’ohun igbagbe
Jabesi d’olori ire
Oriburku d’igbagbe
Gbagbo ninu Oluwa
Ola adara

(Yo ditan dandan)
Yoo d’itan
(Ye sokun mo ore mi)
A d’ohun igbagbe
(Bekun pe dale kan ayo mbo li owuro)
Ilakoja re oni
(O dami loju)
A d’itan
(Fokan re bale Oluwa a se e)
Yoo d’itan
(Ireti si mbe fun o oh )
A d’ohun igbagbe
(Kini isoro re)
Ilakoja re oni
(Dakun b’Olorun so)
A d’itan
(A fun o lomo a kole ayo fun o)
Yoo d’itan
(Amu o se aseyori)
A d’ohun igbagbe
(B’Olorun soni kelekele okan re)
Ilakoja re oni
(O dami loju)
A d’itan oooo

Connect and Follow GospelSongsNG

FACEBOOK TWITTER TELEGRAM

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *