Kabi o osi Kabi o osi Arugbo ojo, ad'agba ma tepa Kabi o osi We worship you, Kabi o osi We worship you, Kabi o osi Arugbo ojo, ad'agba ma tepa Kabi o osi Won o mu o lo 1'edi ki won fi ewe akoko le o lori n'be Ko s'awon to gbinmo po lati so pe eje a fi joba Ab'awon wo lo duro, tan ni won a majoba n'idile won gan Awon wo lo fi o je t'o ffn j'oba kon da wa l'ohun Ta leni isaju to mu o wa s'inu orun Ta leni to fa o ni tete wonu aye pe ko wa daye Oya, k'eniKan fi baba tabi iya re han wa o, aare Kabi o osi Arugbo ojo ad'agba ma tepa l'oruko re Kabi o osi O l'oyun ara re, obi'ra e, o s'ora e loko Ipa ti o se bi l'eere, eni ti o se yi pada Ite re l'orun kii si, onipo ta o le ro l'oye Arugbo ojo ni o, ad'agba ma tepa o Eh.. iwo ni Ka bi o osi Riru omi okun po, nje won o ni dake to ba l'oto Iyanrin nla tun wa, to ba k'aye tan se won o ni pare Igba t'ohun gbogbo ta ko ba di wiwo pale iwo ni o ku o Arugbo ojo, onilu a lu la'torun o Eh eh eh eh eh Kabi o osi O ko d'aye eru b'aye pe kilo fe wa ninu ohun Igba to da aye tan, o m'ohungbogbo s'aye e kon maj'oko won O ti n gbe'biKan ki o to ko orun aare nla ni o, o se tu Ailetuwo Adahunro Adahunso OlunKankun ni o Arugbo ojo, ad'agba ma tepa ooo lwo ni Ka bi o osi Omomo to mo'yun sinu alaboyun to fori feti fenu si O fimu o f'ohungbogbo Sibe e, o de d'igba Kan o bi Se bi bo ba pe ki mimi o ma mi, tani njebe o lwo ni Kabi o osi Agbara re po o ju tara lo, iwo lo da ara Okun re po ko de le pin, oni'mi iye lwo lo mimi'ye si amo lasan to pada wa d'eniyan Eh eh eh eh Kabi o osi Oba ti'n fobaje, Oba to le r'oba Iloye to le ni ko ma mi mo Oba ta o gbodo bi bo ba se'n sise owo re si Ojo n'ro oye n'fun be l'orun ran l'asiko re o Agbara re po o Kabi o osi Mo ni Kabi o osi Kabi o osi Kabi o osi Alagbada ina, Alawotele oorun Eh eh eh Kabi o osi