Lead: Kaabo o kaabo o s'aye o All: Emmanueli kaabo o s'aye o/2X Lead: Olutunu wa kaabo o s'aye o All: Emmanueli kaabo o s'aye o Lead: Oludande wa kaabo o s'aye o All: Emmanueli kaabo o s'aye o [Verse 1] Oba t'abi fun wa nitori t'emi ati re o wa s'aye o lati gbawa la ninu ese wa olutunnu wa ni olusegun funwa alaabo wa ni Emmanueli kaabo o s'aye o [Verse 2] Unto us a child is born a child is given,He shall be called wonderful counsellor,mighty God everlasting Father the king of kings Emmanueli kaabo o s'aye o [Bridge] Araye eyo,araye ejo eyo,ati bi abi olugbala funwa/3X (Interlude by talking drum) Call: Alade alafia kaabo o s'aye o (All): Emmanueli kaabo o s'aye o Call: Olumoran okan wa kaabo o s'aye o (All): Emmanueli kaabo o s'aye o Call: Oba to n fi mimo bora bi aso o kaabo o (All): Emmanueli kaabo o s'aye o Call: Olufe okan mi kaabo o s'aye ooooo (All): Emmanueli kaabo o s'aye o Call: Olowogbogboro ti n yo'mo re loofin aye kaabo o (All): Emmanueli kaabo o s'aye o Call: The lover of our soul kaabo o s'aye oooo (All): Emmanueli kaabo o s'aye o Call: Erujeje ni o kaabo o s'aye ooo (All): Emmanueli kaabo o s'aye o