Igba miran o ma n se mi bii ki n pada seyin Igba miran o ma n se mi bii ki n jowo Re Igba ti 'ji aye ba n ja, bii ki n pada seyin Igba t'okan mi poruru, bii ki n jowo Re Sugbon mo mo, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile Bee ni mo mo, Iwo ni Eni to s'olododo Sugbon mo gba, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile Bee ni mo gba, Iwo ni Eni to s'olododo Igbagbo mi duro lori ododo Re Iwo lapata ayeraye, ibi isadi mi B'okan mi poruru, ko le p'ase Re da lailai Iwo s'olododo, mo si mo O ni Alaanu Igbagbo mi ro mo O, Iwo ni agbara mi Oke ni mo f'okan si, ibi ti iranwo gbe wa Fun mi lokun atoke wa, ki n mase pada seyin Ki n ma sise ninu iriri, ki n mase jowo Re Tori mo mo, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile Bee ni mo mo, Iwo ni Eni to s'olododo Tori mo gba, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile Bee ni mo gba, Iwo ni Eni to s'olododo Iriri aye a maa fe so 'yan d'eni o ni 'gbagbo Sibe mi o gbeke l'ohun kan leyin agbara Re Ogbon ori eeyan o le roo ja, eto too ni lailai Koda b'okan mi se 'yemeji, ileri too se o duro Abrahamu, Serah, won rerin looto ntori o dabi pe yeye ni Sibe won d'eni itokasi fun ibukun pipe Fun mi lokun atoke wa, Iwo ni Alatileyin Ki n ma subu, ki n la ajo yi ja, ki n mase jowo Re Tori mo mo, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile Bee ni mo mo, Iwo ni Eni to s'olododo Tori mo gba, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile Bee ni mo gba, Iwo ni Eni to s'olododo Mo mo daju Iwo ni Eni ti kii ko ni sile Bee ni mo gba, Iwo ni Eni to s'olododo Tori mo mo, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile Bee ni mo gba, Iwo ni Eni to s'olododo Igba miran o ma n se mi bii ki n pada seyin Igba miran o ma n se mi bii ki n jowo Re Igba ti 'ji aye ba n ja, bii ki n pada seyin Igba t'okan mi poruru, bii ki n jowo Re Sugbon mo mo, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile Bee ni mo mo, Iwo ni Eni to s'olododo Sugbon mo gba, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile Bee ni mo gba, Iwo ni Eni to s'olododo Igbagbo mi duro lori ododo Re Iwo lapata ayeraye, ibi isadi mi B'okan mi poruru, ko le p'ase Re da lailai Iwo s'olododo, mo si mo O ni Alaanu Igbagbo mi ro mo O, Iwo ni agbara mi Oke ni mo f'okan si, ibi ti iranwo gbe wa Fun mi lokun atoke wa, ki n mase pada seyin Ki n ma sise ninu iriri, ki n mase jowo Re Tori mo mo, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile Bee ni mo mo, Iwo ni Eni to s'olododo Tori mo gba, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile Bee ni mo gba, Iwo ni Eni to s'olododo Iriri aye a maa fe so 'yan d'eni o ni 'gbagbo Sibe mi o gbeke l'ohun kan leyin agbara Re Ogbon ori eeyan o le roo ja, eto too ni lailai Koda b'okan mi se 'yemeji, ileri too se o duro Abrahamu, Serah, won rerin looto ntori o dabi pe yeye ni Sibe won d'eni itokasi fun ibukun pipe Fun mi lokun atoke wa, Iwo ni Alatileyin Ki n ma subu, ki n la ajo yi ja, ki n mase jowo Re Tori mo mo, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile Bee ni mo mo, Iwo ni Eni to s'olododo Tori mo gba, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile Bee ni mo gba, Iwo ni Eni to s'olododo Mo mo daju Iwo ni Eni ti kii ko ni sile Bee ni mo gba, Iwo ni Eni to s'olododo Tori mo mo, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile Bee ni mo gba, Iwo ni Eni to s'olododo