Esu to ba gbemi, too gbe mi, too gbemi Esu to ba gbemi, oo le lami mole o Esu to ba gbemi, too gbe mi, too gbemi Esu to ba gbemi, oo le lami mole o Jesu ti la o mole o, oo le lami mole Jesu ti la o mole o, oo le lami mole Jesu ti la o mole o, oo le lami mole Jesu ti la o mole o, oo le lami mole Iya to ba gbe mi, too gbe mi, too gbemi. Iya to ba gbe mi, oo le la mi mole o Ese to ba gbe mi too gbe mi, too gbemi. Ese to ba gbe mi, oo le lami mole o (Adlibs) Nitori naan, Olorun si ti gbe ga gidigidi O si ti fun ni oruko to ju gbogbo oruko Pe ni oruko Jesu ni ki gbogbo eegun ki o maa kunle Awon ni tin be ni orun, ati awon ni tin be ni Ile Ati awon ni tin be nisale ile. Ati Pe ki gbogbo ahon ki o maa jewo Pe Jesu Kristi Ni oluwa wun ogo Olorun Baba Oruko Jesu ni oruko to ju gbogbo oruko love Oun ni olugbala re, Oti ku, ositi ji nde Oti jiya Nitori tiwa He Paid the price on the cross Oti fun wa ni isegun, Jesu mi oruko re Jesu ti la o mole o, oo le lami mole Jesu ti la o mole o, oo le lami mole Esu to ba gbemi, too gbe mi, too gbemi. Esu to ba gbemi, oo le lami mole o (Adlibs) Ti o ba Lee gba ise ori igi agbelebu yii gbo Ti o si if aye re fun, ko si Oun ti Esu Lee fi o se. Tabi oun ti o Lee muwa si aye re, ose lasan ni Iwo saa ti gba ni Oluwa ati igbala re Yoo si ko Ese re sile, kiyoo siji bowo Yo O si fun o ni isegun Ko wa si, be esu, iya, Arun, ese se le gbe o to. Kole lao mole Rara, tori Pe asegun ni o ninu Jesu Kristi Oluwa Jesu ti la o mole o, oo le lami mole Jesu ti la o mole o, oo le lami mole Jesu ti la o mole o, oo le lami mole Jesu ti la o mole o, oo le lami mole