[Verse 1] Jesu olufe okan mi Jesu Olugbala okan mi O ta eje re sile Fun irapada mi [Ibukun atope ni foruko re titilai Iyin atogo ni, forukore titilai [Verse 2] Jesu mi olugbeja mi Jesu loluso aguntan mi O wa pelu mi nigba gbogbo O rin pelu mi emi ki yo beru [Chorus] Ibukun atope ni foruko re titilai Iyin atogo ni forukore titilai Ibukun atope ni foruko re titilai Iyin atogo ni forukore titilai Ibukun atope ni foruko re titilai Iyin atogo ni forukore titilai Ibukun atope ni foruko re titilai Iyin atogo ni forukore titilai