Mo wo ka gbogbo aye pa Koma de seni ti mo lo pe ni mimo Gbogbo omo adari hurun pata pata Iwa ibaje ni won mi wu kiiri Oro aye toju su mi ohohohoh Opin aye ti de tan ore mi gbo Emi mimo ni'e je a jo beere fun Kaba le dejoba orun si mi ohoh Emi mimo ni mo fe Je ko ba le mi oluorun Ebe mi ma re loni o baba Emi mimo ni mo fe Je ko ba le mi oluorun Ebe mi ma re loni o baba Mi o fe waye lasan Bi ejo ori apata Ebe mi ma re loni o baba Emi mimo ni mo fe Je ko ba le mi oluorun Ebe mi ma re loni o baba Iwa ese ma mi gbokun si ni abi eyin ori ni Iwokuwo logbode okunrin atokunrin tun ti n fe ra won Kini pasito n wa re le alawo (oma se oo) Eemo lukutu pebe oko tun faya re rubo (ha iru ife wo leyi oo) Emi mimo le mi n fe jeko ba le mi Oluorun Ebe mi ma re loni o baba Emi mimo ni mo fe Je ko ba le mi oluorun Ebe mi ma re loni o baba Emi mimo ni mo fe Je ko ba le mi oluorun Ebe mi ma re loni o baba Mi o fe waye lasan Bi ejo ori apata Ebe mi ma re loni o baba Emi mimo ni mo fe Je ko ba le mi oluorun Ebe mi ma re loni o baba Aye n pare lo ore mi 00 Mase woro aye Opin aye lawa yioo Emi n bo kankan ere mi nbe pelumi sa Lolugbala wi funwa Otilo la ti lo pese aye sile feni bale duro