Oro Oluwa, ko ni lo lai se Ife Oluwa, ko ni lo lai se Imo Oluwa, ko ni lo lai se Oun mo ri e, ko ba mi leru Oun mo ri e, ko gbin mi lokan O ti e ye ko fo mi laya Sugbon mo ti pinu, la ti di mu Olorun o dodo ni Si be mo pinu lati mu okan ro Tori mo mo pe Oro Oluwa, ko ni lo lai se Ife Oluwa, ko ni lo lai se Imo Oluwa, ko ni lo lai se Ko ni lo lai se Ko ni lo lai se o Igbagbo e , lo gbe ileri awon ase mu Ibanije le wa, sibe oro e ase Ikoro le ko , sugbon adun la ja si Mo gboju mi sa pa oke Iranwo mi be lati Olorun ododo Idaniloju mu ireti wa tori mo mo pe Oro re si mi, ko ni lo lai se Ife re si mi rere ni, ko ni lo lai se Imo Oluwa o, ko ni lo lai se Olorun ki se eniyan to ma n se’ke O ti wi be, a se be Dandan lo n je Bo ti le wu ko ri, oro re ase Olepe di e, sugbon pe ko ye…hmmm, rarara Ofifo a dopo Irora a di ironu, ka ni ireti Adun, a po, a pe Adirigi, aferegere, a pe Igbagbo re ko ma mi se, ileri a se Igbagbo re ko ma mi se, ileri a ma se Igbagbo re ko ma mi se, ileri a se Oun o ri le ma ba o leru Oun o ri le ma mi e lokan O ti e le ma fo o laya Sugbon ko ti pinu la ti di mu Olorun o dodo ni Si be pinu lati mu okan ro Tori a jo mo ni pe Oro re si wa, ko ni lo lai se Ife Oluwa si wa rere ni, ko ni lo lai se Imo Oluwa o, ko ni lo lai se Oko jo pe o buru ni, ko ni buru fun o omo eniyan Oro re ki ye, ko ni lo lai se Mojukuro ninu juju to yoka loju re, iranwo wa….mo ju re soke, Ko ni lo lai se Gba lolu, gba loluto, gba loluto ati oludari, oro e rere ni ko ni lo lai se eh Oro Oluwa o, ko ni lo lai se Ni gba ti mo gbeke le olu emi, mi o ni ri ituju kan lailailai ko ni lo lai se Mo gba lo luranlowo mi, oun lo ran mi lowo, oro re ko ni lo lai se ko ni lo lai se Oti wi be, a se be fun mi Mo n duro, mo n duro ko ni lo lai se Eh eh Oro Oluwa, ko ni lo, ko ni lo, ko ni lo lai se Gba be, gba be, gba be ko ni lo lai se Oro re si wa rere ni ko ni lo lai se Tu ju re ka, tu ju re ka , oro re ko ni lo lai se ko ni lo lai se Bi o ti le wu ko ri, ko ni lo lai se gba be hmmm oro Oluwa