Nipa ipa ko, kii s’agbara l’oro se ri b’o se ri B’o ti wu ko ri Oluwa s’olododo f’awon to gba A gbo Oye aye o ye ni to sugbon o da wa loju Alaanu l’Olorun wa A gbe ni leke, Oluke ni, Oluyan ni sola Aseyiowu O se o Baba t’o fi wa dara iyanu (Iba Iba Iba) Iba o Iba f’Olorun Eledumare to l’ogo oooo (iba) Iba Iba Iba naa ni o (Iba o) Iba Iba Iba o A juba, a juba, f’Olorun to ni gbogbo ogo, Oun ni (Iba o) Iba l’awa f’aye wa ju oo (Iba o) Iba, a juba Re, Iwo nikan lo ni gbogbo ijuba a wa (Iba o) Iba Iba Iba Ope ni fun o Edumare, Oba to laye Adani magbagbe Oba Oke to segun fun wa Bi ko ba se ‘Wo too seyi fun wa ki la a ba wi o Ope wa ree o, Oba to to gb’oju le A mo riri oore t’Oo se fun wa o, Oba to to gb’oju le Okeere ni mo gbe wa o, mo gburo ise Oluwa Ta lo dabi Re ninu aanu, adani ma gbagbe eni Bi’da keji ba sele, Oo sa ma j’Olohun lo ni O ka wa m’awon t’Oo pe, t’Oo yan Oba to to gb’oju le O ka wa m’awon t’Oo s’aanu fun A o le dupe tan lai lai lai lai You are the Lord above all the earth Kabi o o si o You are the Lord above all the earth Kabi o o si o Oju mi ti ri, eti mi ti gbo Iyanu Re yi aye ka Mo gbo ninu eri awon eniyan mimo Mo ri ninu itan, emi gangan ni itan Gbogbo ise Re daa da’a da’a da’a ni Aburu kankan o t’odo Re wa Ohun gbogbo lo le yi pada Sugbon rara t’ododo Re ko Kabiyesi oooo, mo se ba Re Oba to ju gbogbo oba lo Kabiyesi ooo Kabiyesi o mo se ‘ba Re Oba to ju gbogbo oba lo Afuye gege ti o see gbe Jigbinni jigbinni bi ate ileke Kabiyesi o mo se ‘ba Re Oba to ju gbogbo oba lo Afuye gege ma ma see gbe Jigbinni jigbinni bi ate ileke Kabiyesi o mo se ‘ba Re Oba to ju gbogbo oba lo Mo se ‘ba Re o, mo se ‘ba Re Mo f’ori bale mo gb’owo soke Mo se’ba Re o, mo se ‘ba Re Ni ‘rele okan mi ni mo wari Kabiyesi o mo se ‘ba Re Oba to ju gbogbo oba lo Kabiyesi o Kabiyesi o mo se ‘ba Re Oba to ju gbogbo oba lo Aigbagbo bila temi l’Oluwa Oun yoo si dide fun igbala mi Ki n sa ma gb’adura Ki n sa ma gb’adura Oun o se ‘ranwo ‘Gba Krist’ wa l’odo mi ifoya ko si B’ona mi ba su, Oun lo sa n to mi Ki n sa gboran sa Oun o si pese B’ona mi ba su o, Oun lo sa n to mi Ki n sa gboran sa Oun o si pese Bi ‘ranlowo eda Bi ‘ranlowo eda gbogbo saki Oro t’enu Re n so yoo bori dandan Hallelujah Hosanna Hallelujah Hossanah Hallelujah l’awon orun nke Hossanah Awa aye naa nke tiwa, hallelujah Hossanah Hallelujah Hossanah (hossanah hossanah l’awa nko) Hallelujah (Hossanah) Gbogbo iseda n f’ori bale f’ooko Re, Hallelujah Hossanah Hallelujah Hossanah Our Father We bless You Olutoju wa, we bless You We bless You Eni to l’emi to fun wa mi, we bless You We bless You Eni t’O fi ‘ranwo fun wa, we bless You We bless You Eeeh Oluwa, Eeeeh ehhh Oluwa Eeeeh Oluwa o b’ona ba su Oluwa f’ona han wa, Oluwa o Eeeh Oluwa, Eeeeh ehhh Oluwa o Eeeeh Oluwa o b’ona ba su Oluwa f’ona han wa, Oluwa o Ife t’O fi han ko je ki n ro pe Yio fi mi sile ninu wahala Oun to mu mi de bi s’olododo lati sun mi siwaju Ko ni fi mi sile bo ti le wu ko ri o Iranwo ti mo si Iranwo ti mo si n ri lojojumo O ki mi l’aya pe emi yoo laaja Olorun agbaye You are mighty Olorun to wa ninu awon orun to ju awon orun lo (You are mighty) Ori obiri aye lo n gbe imole lo fi saso bora o (You are mighty) O f’orun se ‘le, O f’aye s’apoti itise maa s’ola Re lo (You are mighty) You are mighty, You are wonderful, You are awesome, oruko Re niyen (You are mighty) Olorun agbaye (You are mighty) Sebi ‘Wo lo f’oju orun saso bora Olorun agbaye o, You are mighty o Olorun agbaye o You are mighty Sebi ‘Wo lo f’oju orun saso bora Olorun agbaye o, You are mighty o Oruko Oluwa ile iso agbara ni Olododo sa wo’nu re, o ri iye Emi naa, mo sa wo’nu re, mo ri iye Oruko Re ti niyin to (Oluwa Oluwa) Oluwa, Oluwa wa, oruko Re ti niyin to Oluwa Oluwa Oluwa Oluwa, Oluwa wa, oruko Re ti niyin to Alagbara l’Olorun wa Agbara agbara agbara yi po o, agbara Oba to ba riru omi okun wi, agbara Re po Agbara agbara agbara yi po o, agbara A wo ‘gba aarun, ma gb’eje l’ooko Re Agbara agbara agbara yi po o, agbara Oba to f’aanu tan ‘mole s’ona awon to gb’oju s’oke si Agbara agbara agbara yi po o, agbara O f’agbara gba ni lowo alagbara gbangba ti n f’owo agbara je ni niya Agbara agbara agbara yi po o, agbara Gbogbo iseda n wariri ni’waju agbara Re Agbara agbara agbara yi po o, agbara Iba o Iba f’Olorun Eledumare to ni gbogbo ogo (Iba) Iba Iba a (Iba) A juba, a juba, gbogbo ijuba wa tire ni (Iba) Olorun to ni gbogbo ogo, iba f’ooko Re (Iba) Gbogbo iseda n f’ori bale ni’waju Re (Iba) Iba Iba Iba a Ise Re po, o po, o po, o po gaan ni (Iba) Awon ise iyanu t’Oo ti se, ta lo le ka won tan? (Iba) Ta lo le so ewa Re to po, to po gaan ni? (Iba) Iba Iba Iba Iba (Iba) Gbogbo eemi mi, gbogbo wiwa mi, tire lo je, mo juba (Iba) Titi aye ni ma ma se’ba Re lojojumo (Iba) Maa sin O d’opin igba mi, Iba Iba (Iba) Iba aaa