Iba re ni ma f’aiye mi ju Sisin oo lemi a figba m ise Shebi iyen nooni Iyen gangan sha lo da mi fun Eni aiye riaye to nigba mi o Ogo f’oko re Afuye gege ti o she gbe Jigbin ni jigbin ni bi ate ileke Kabiyesi mo se’ba re Oba to ju gbogbo oba lo Afuye gege ti o she gbe Jigbin ni jigbin ni bi ate ileke Kabiyesi mo se’ba re Oba to ju gbogbo oba lo Mo se’ba re o, mo se’ba re Mo fori ba’le mo gbowo soke Mo se’ba re o, mo se’ba re Nirele okan mi mo wa ri Kabiesi o mo se’ba re Oba to ju gbogbo oba lo Mo se’ba re o, mo se’ba re Mo fori ba’le mo gbowo soke Mo se’ba re o, mo se’ba re Nirele okan mi mo wa ri Kabiesi o mo se’ba re Oba to ju gbogbo oba lo Ta lo le so Ta lo le ka won Awon irawo t’owa loju orun Egbe isiro le won Ke so fun wa Awon erupe inu okun Tal o le so Ta lo mo’ye Ewa iseda toyi wa ka Iyanu fun dudu Iyanu fun fufun Ose fe ni to gbon ati eni to go Kaabiesi o mo se ba re o Oba to ju gbogbo oba lo Afuye gege ti o she gbe Jigbin ni jigbin ni bi ate ileke Kabiyesi mo se’ba re Oba to ju gbogbo oba lo Mo se’ba re o, mo se’ba re Mo fori ba’le mo gbowo soke Mo se’ba re o, mo se’ba re Nirele okan mi mo wa ri Kabiesi o mo se’ba re Oba to ju gbogbo oba lo Gbo gbo aye gbohun soke ni mu ewa won, Won f’ogo fooko re Ohun gbogbo fiyin fun o o Iwo nikan l’oba t’ologo Oju mi tiri Eti mi ti gbo Iyanu re yi aye ka Mo gbo ninu eri awon eniyan mi mo Mori ninu itan Emi gangan nitan Gbogbo ise re dadada ni Aburu kankan o todo re wa Ohun gbogbo lole yi pada Sugbon rara tododo re ko Kabiyesi o mo se’ba re o Oba toju gbogbo oba lo e Afuye gege ti o she gbe Jigbin ni jigbin ni bi ate ileke Kabiyesi mo se’ba re Oba to ju gbogbo oba lo Afuye gege mama se gbe Okan mi pongbe mi mo si Emi wao mo n wa o si oo hmm Oba toju gbogbo oba lo Ogo re yi aye ka Emi se’ba, mo se’ba o Mo fori ba’le ni waju ite aanu Oba agbanilagbatan Oba adani magbagbe eni Mo wa ri Emi se’ba re o oh oh oh Oba to ju gbogbo oba lo hmm Oba to ju gbogbo oba lo Oba toju gbogbo oba lo sara re re o Ehn kabiyesi mo se ba re o Emi yi o ma fi bukun fun o lojojumo iwo nikan loni i Ni gbogbo igba, ni gbogbo asiko, okan mi yio ma f’ogo f’okore Oluwa orun ohun aiye ewa re yi aye ka, a n f’ogo f’okore hmm Mo jewo mo jewo re, iwo nikan l’oluwa ko se lomiran leyin re You are beautiful beyond description, ewa re koja ogbon ori You are wonderful beyond comprehension, iyanu re koja oye