Pre-Chorus Duro ti mi o, Ololufe Ife ti ko labukun ni ko ba mi lo Duro ti mi o, Ololufe Ife ti ko labawon ni ko ba mi lo Chorus (2x) Ife bi eji owuro latagbala eledumare lo ti se wa Ife to toro minimini Ti abawon aiye kan, o le baje o Ololufe feran mi, lai se itan o Hook (2x) Fe mi bi oju ti fe imu Fe mi bi irun ti fe ori Fe mi bi eyin ti fe nu Fe mi temi temi Fe mi tokantokan Fe mi tara tara Ololufe feran mi lai se itan o (Repeat chorus) (2x) Verse 2 Ba mi se otito, mo fe o toto Ba mi se ododo, mo fe o pelu ododo Ba mi se otito, mo fe o toto Ba mi se ododo, mo fe o pelu ododo Bo ogiri o ba lanu, alangba o le wo ogiri (2x) Eleda lo yan wa papo, esu o ni ya wa o (Repeat chorus) Verse 3 Ama lowo lowo Ama bimo le mo Ama se ayo mo ayo Ama se ola mo ola Ka sha mu ife eledumare se lai se itan (Repeat chorus) Verse 4 Gba imoran mi, Ololufe mi Oluranlowo la fi mi se fun o, lati orun wa Fe ti si omoran mi, Ololufe mi Gba imoran mi, Ololufe mi Oluranlowo la fi mi se fun o, lati orun wa Ka jo rin, ka shogo fun Oruko Olorun Alabarin la fi mi she fun ni, lati orun wa Mo kan kuro ninu esan aiye, etan o da nkankan fun ni Ife ati ope lo le mu alaiye je lai labawon Mo kan kuro ninu esan aiye, etan o da nkankan fun ni Ife ati ope lo le mu alaiye je lai labawon