Skip to content
Home » Owolabi Ayoola Songs » Debra Crown-Olu – Korin Si Oluwa Ft. Laolu Gbenjo

Debra Crown-Olu – Korin Si Oluwa Ft. Laolu Gbenjo

Korin Si Oluwa Download, Stream, Video and Lyrics | Debra Crown-Olu Ft. Laolu Gbenjo

Debra Crown-Olu UK Based Nigerian Gospel Minister, aka Evangelist Debby Mojisola Adedapo-Olukayode releases another powerful brand new single titled “KORIN SI OLUWA” which means “Sing unto the Lord” and she features Nigerian Gospel Special Alujo Minister, Laolu Gbenjo.

This is their first collaborative effort, as they offer deep praise to God on this melodious alujo-tempo. Laced with essential of Africa percussion

Korin Si Oluwa” is a Victory Praise to almighty God, declaring His awesomeness, strange works, strange acts and His mighty hands which gives us victory over all situations. According to Exodus 15 and Psalm 3:3 (Ekisodu 15). It is sang in Yoruba Language.

Music Producer- Tobass Adolphus Records.

Korin Si Oluwa” is now available on digital stores;

Download and Stream Korin Si Oluwa By Debra Crown-Olu Ft. Laolu Gbenjo
Download and Stream Korin Si Oluwa By Debra Crown-Olu Ft. Laolu Gbenjo (MP3)

STREAM OR DOWNLOAD / BUY AUDIO

GET AUDIO

Album : Debra Crown-Olu (MP3)

STREAM OR DOWNLOAD / BUY ALBUM

Video Lyrics : Korin Si Oluwa By Debra Crown-Olu Ft. Laolu Gbenjo

Lyrics for Korin Si Oluwa By Debra Crown-Olu Ft. Laolu Gbenjo
KORIN SI OLUWA (I will sing unto the Lord)

Chorus:
Emi o kọrin si OLUWA, nitoriti o pọ̀ li ogo:
ẹṣin ati ẹlẹṣin on li o bì ṣubu sinu okun pupa.

OLUWA li agbara ati orin mi,
on li o si di ìgbala mi:
eyi li Ọlọrun mi, emi o si fi ìyin fun u;
Kabioyesi mo se iba re
Emi o kọrin si OLUWA,

Chorus:

Emi o kọrin si OLUWA, nitoriti o pọ̀ li ogo:
ẹṣin ati ẹlẹṣin on li o bì ṣubu sinu okun pupa.

Oluwa, li asà fun mi; ogo mi;
olugbe ori mi soke.
Emi fi ohùn mi kigbe si Oluwa,
o si gbohùn mi lati òke mimọ́ rẹ̀ wá.
Emi o kọrin si OLUWA,
Oba to ‘n be ninu orun

Response: gbega mi o le sai gbega titi lai.

O ran omo ni se fayati
Response: gbega mi o le sai gbega titi lai.

You are bigger than the biggest
Response:
Olowogbogboro ti ‘n gba omo re lofin

Response:

A se kabiesi re eladumare tewogbope (Interlude (Omo egbala gbo in so ke).

Oba to ti wa o, k’ aye to wa
ti si tun ma wa nigba ti aye ko no si mo

Mo ni, Oluwa n’ be bi ti ati Jo

Response: A wa la o sin baba bi ta ti jo.

Bridge:
Ologun li OLUWA; OLUWA li orukọ rẹ̀.
ọwọ́ ọtún rẹ li ogo ninu agbara:
ọwọ́ ọtún rẹ fọ́ ọtá tútu.
Emi o kọrin si OLUWA,

Mo korin hallelujah
Mo ke hallelujah
Ona to di ti la o
Oluwa la ona ni bi to ko so na
Ona to di ti la o
Ogo oluwa won la ye mi

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *