Skip to content

Adejumoke Dada – Alagbada Ina [MP3 and Lyrics]

Alagbada Ina Download and Lyrics | Adejumoke Dada

Nigerian Gospel Music Minister, Worship Leader, Adejumoke Dada releases powerful single titled “Alagbada Ina“.

Download Alagbada Ina By Adejumoke Dada

Lyrics for Alagbada Ina By Adejumoke Dada

Alagbada ina alawotele orun,
Oba nla  alara gbayida o ,
Eni kerin ninu ina ileru,ina nla ton joo igbe oo,
Ti igbe o si runn.

Otun ni o, olorun aji dara,
Otun Len deru aye eda gbogbo,
Lotun lotun Len shi ilekun ojo gbogbo,
Aji dara fi aye mi da ara ire.

Bawo wo lo sheje ti omi fi de inu agbon?
Ona wo lo gbegba ti iji ole da omi inu agbon nu,
Iyan eti okun ta lo le ka won,
Gbogbo omi   inu okun mo ni how many liters ni gan?

Be sini omi n be lorun,o gbe gbogbo aye so ri ikun omi,
oda ile osi
Tun da awon oke,
Aji dara iwo la lara gbayida oo.

Ina nla to pin okun niya,
Ina nla to wo odi jeriko,
Ina nla ti o te ogun ayemi riiii,
Ina nla ton joo igbe o,
Ti igbe osi runn.

Oba ha 4x
Oba ha 5x
Oba ha 4x
Oba haaa iyanu ni ooo..

Download Alagbada Ina By Adejumoke Dada (MP3)

GET AUDIO

Connect and Follow GospelSongsNG

FACEBOOK TWITTER TELEGRAM

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *