Oju Koni Timi Download, Stream, Video and Lyrics | Adedoyin Mayungbe
Oju koni timi
Ota koni yomi
Ise mi alere
Ojo mi adale
Ma gunle layo
Ni oruko JesuOju koni timi
Ota koni yomi
Ise mi alere Dale
Magunle layo o
Loruko Jesu
Download and Stream Oju Koni Timi By Adedoyin Mayungbe (MP3)
DOWNLOAD / STREAM AUDIO BOOMPLAY
DOWNLOAD / STREAM AUDIO AMAZON
Video Audio : Oju Koni Timi By Adedoyin Mayungbe
Lyrics for Oju Koni Timi By Adedoyin Mayungbe
Oju koni timi
Ota koni yomi
Ise mi alere
Ojo mi adale
Ma gunle layo
Ni oruko Jesu
Chorus:
Oju koni timi
Ota koni yomi
Ise mi alere Dale
Magunle layo o
Loruko Jesu
Emi o ni bojo olojo lo
Ise mi alere oooo
Magunle layo
Loruko Jesu
Loruko Jesu ni mo so a o ni gba se mi se eh ehn
Magunle layo
Loruko Jesu
Mo ma ko re oko dele ola mi adara aaa
Magunle layo
Loruko Jesu
Oju o ni timi laye
Loruko Jesu ni mo toro
Magunle layo
Loruko Jesu
Oju koni timi
Ota koni yomi
Ise mi alere
Ojo mi adale
Ma gunle layo
Ni oruko Jesu
Chorus:
Oju koni timi
Ota koni yomi
Ise mi alere Dale
Magunle layo o
Loruko Jesu
Emi o ni bojo olojo lo
Ise mi alere oooo
Magunle layo
Loruko Jesu
Loruko Jesu ni mo so a o ni gba se mi se eh ehn
Magunle layo
Loruko Jesu
Mo ma ko re oko dele ola mi adara aaa
Magunle layo
Loruko Jesu
Oju o ni timi laye
Loruko Jesu ni mo toro
Magunle layo
Loruko Jesu
Leave a Reply